Eulogy
Eulogy (Oriki) –
Elegushi, Ekan Mebi
Omo Iroko lawe
Omo Olofin Ajaye
Omo Isan Arewa Ejo
Omo Elegba Meta Lopo-po
Omo Ota Meta Meji Lagbadan
Ikan L’eremi
Omo Epo Were-were
Lojude Ilasan
Won ki nfi Oko Ro
Won kin fi Ada Ro
Bi a Ko Ba Ro
A Ko Gbodo Kuro Nibe
Omo Manu Manu
Temi Nikan ko
Omo Akenigbo
Ki Eru Ki Oba Ara Ona
Omo Apekan
Ma fun Obirin je
Omo A Sa Ni Poriki Poriki
Omo Asa Majumu
Omo Adamu Sere
Omo Adese Sere
Omo Adese Mu Ye Ge
- ELEGUSHI RECEIVES LASAA MANAGEMENT
- Tinubu, Sanwo-Olu, Ooni, Elegushi, Others At Coronation of Oniru of Iruland
- OBA ELEGUSHI SUPPORTS LAGOS STATE HIV/AIDS CONTROL AGENCY
- Igbinedion University, Okada Conferred on Oba Elegushi an Honorary Doctorate Degree in Public Administration
- HRM Oba Saheed Elegushi Becomes a Major Donor to The Rotary Foundation of Rotary International
- Adewale Odumuyiwa on King’s Profile
- Adeleke Afolabi on King’s Profile
- Oyebola Rokeeb (Ariwo Kakaki) on The King
- ADETORO TAIWO on King’s Profile
- Adebowale James on Genealogy of the Monarchy
Contact Info: Oba Elegushi Palace, Km 13 Eti-Osa Expressway, Eti-Osa, LGA, Lagos, Nigeria
Email: contact@hrmelegushi.org, chiefofstaff@elegushi.online